عرض المقال :Writing Speaks
  الصفحة الرئيسية » مـقـالات الموقـــع » كشف البلية بفضح الأحمدية » Non - Arabic Articles » Yoruba

اسم المقال : Writing Speaks
كاتب المقال: webmaster

IGBESI AIYE OGBENI MIRZA GHULAM-

OLORI IJO AHMADIYYA

 

    IGBA EWE OGBENI MIRZA QADIANI

  “Abi mi ni odun 1839 tabi odun 1840A.D. Emi jekan ninu ibeji ti won bi. Obinrin ni ikeji mi ti oruko re nje Jannat (ti o tumosi alijanna). Ninu asotele mi, e ori “ya Adam Uskun antaa wa zaujoka al-jannah, ti o jade ninu iwe kan ti anpe ni Braheen Ahmadiyya ni oju ewe 496 ni nkan bi ogun odun sehin, gbolohum ‘jannat’ na ni aripe omobinrin to je ikeji mi ni onje oruko na ati wipe omobinrin na jade laiye lehin osu meje ti abi.” (Ninu iwe kan ti ogbeni Mirza Ghulam Ahmad Qadiani kotiasi pe akole reni “Tiryag-ul-Quloob, Roohani Khazain. Vol. 15, oju ewe 479)” Mirza Ghulam Ahmaat so wipe: “Baba mi tonje Mirza Ghulam Murtuza je enikan to ma mgbe ile fun a won Ayalegbe. Ni igba ewe mi mobere iwe kika nigbatimo di omo odun mefa si odun meje. Eniti won gba lati je oluko mi ni enikan ti o je ara Persia. O ko mi ni Quran kika pelu awon iwe miran to je ti ede Persia. Oruko re ni Fazi-llahi. Nigbati modi omo odun mewa, oluko ti Arabic ti nje Mouldi ni eni ti won gba lati je oluko mi. oruko re Fazl Ahmadi. Igbati modi omo odun metadinlogun si mejidilogun, mo nin anfani lati gba eko lati odo baba to bimi lomo. Won komi ni ijinle ede, ogbon ati oye segun. Awon iwe segun ni baba mi fi komi. Nitori aile ara mi, baba mi a ma so fun mi wipe kin ma se kawe pupo.”

   “Nipa awon abule ti ijoba oyinbo Gesi fipa gba, baba mi gbe ijoba losile ejo nilu oyinbo lati gba awon abule na pada.  Won mu mi gege bi enikan ti yio duro rojo nile ejo lori oro na. Biotile je pe kotemilorun lati dasi iru oro be. Sugbon won semi ni tulasi lati bojuto awon oro na. Ni igba pipe seyin, mo ti sise fun bi odun die nile ejo ti anpe ni kotu Siakot gege bi akowe ti mosi mgba Rs 15 ni ososu. Leyin na mofise sile lati koju si oro ejo tio wa ni kotu.   Lore, kore ni emi a ma ronusi oro ilu kuran. Nigbati mo di omo ogbon odun si marun din logoji, baba mi jade laiye. Mo wa nilu Lahore nigbana. Lehin iku baba mi, mo bere si jiroro pelu Olorun.”  (iwe kan tiampe ni kitab-ul-Bariayh ni oju ewe 134 – 136, iwe kan bakanna ti ogbeni Ghulam Ahamad Qadianiko tiampe ni Roohani Khazain Vol. 13 tioju ewe 180; Tuzuk-E-Ahmadi tiakoni ede Akhbar-Al-Hakam Qadian  vol. 37 N0. 18519 ni ojo 21-28 May 1934 AD).

    (Iwe na ni akole re lo bayi “Mirza salo pelu owo awon osise ti oti fise sile”).

    “Ni oruko Olorun – Alanujulo – Olore – Ofe. Hazrat Waalida Sahiba, eni owo, iyawo Alaponle fun ogbeni Mirza Ghulam-so fun mi pe nigba kan, lasiko igba omode, ti arakunrin ti ampe ni Hazrat Maseeh Mowood lo gba owo osu ti ansan fun awon to ti fise sile (pension) bakanna ni arakunrin Imama deen to nse ebi Ghulam tele won si jo gbimo po lati na owo na ni basu basu. Eleyi muki arakunrin Imamdeen salo, bakanna ogbeni Hazrat Maseeh Mowood ko wale ni tori itiju. Lehin na ni o bere si se ise nile ejo (court) lodo Alakoso ni lu Sialkot pelu owo osu to kere pupo.

    IFASEYIN EBI

  “Baba to bimi lomo ti oruko re nje Mirza Ghulam Murtuza, won sa ba ma joko lori aga kani odo Gomina Dar bar, eniti o feran ijoba Gesi Osije eni tio laya pupo, to fije wipe ni gbati wahala kan besile ni odun 1857 A.D. ose iranlowo fun ijoba ti oyinbo tobe ti o ra esin adota pelu awon ajagunta adota. Bayi ni ogo ile wa se beresi faseyin lojojumo titi ofi di asiko tiwa, ebi ti wa si wa gege bi onile ti o ma gbele fun Ayalegbe.” (Ninu iwe tohafa-e Qaiser, Roohani Khazain vol. 12 ni oju ewe 270 – 271) “Ijoba Britain fi tulasi gba ile wa, won si nsan owo pension Rs700/- ni odun kan. Igba to ya, won dinkusi Rs180/- nigba ti baba to bi baba mi ku. Won si da owo na duro leyin iku aburo baba mi.” E wo nu iwe ti anpe ni (Seerat-ul-Mahdi apa kini oju ewe 41, eyi ti Ogbeni Mirza Basheer Ahmad ko nipa Mirza Ghulam Ahmad Qadiani).

   AWON ARUN TO NSE ENI ASELERI RE

  “Eyin ogbeni Ghulam Ahmad Qadiani a ma dun to fi je pe lekokan amaro. Okan ninu eyin na yo so nso ti o fi dipe arun ulzer ti nse lori ahan e.”  (E wo nu iwe apakeji ti Seerat-ul Mahdi oju ewe 135 eyi ti Ogbeni Basheer Ahmad ko lori Ogbeni Ghulam Ahmad Qadiani) “Nigba kan, o subu lati ori window osi fi apa osi sese ti o siri be titi igbehin aiye re.”

  AIPE ARA (OKOBO)

  “Kosi agbara fun opolo mi fun igba pipe lehin ti mose igbeyawo. Eyin lo mumi ma ro wipe nkan omokunrin mi kosise. Won wipe okobo ni mi.” oro yi wa ninu iwe ti Ogbeni Ghulam Ahmad Qadiani ko ni ojo 22/2/1887 ti o si wa ninu iwe kan ti a mpe ni Maktoobate Ahmadiyya, vol. 5, oju ewe 14 ari eleyi gba lodo Khalid Wazirabadi.

  “Ni asiko ti mo se igbeyawo, okan mi ati opolo mi ni kosi agbara fun, koda, oyi amakomi fun igba pipe, nitori idi eyi, mo banuje pupo, eyi tio tunje ki ma le se asepo pelu iyawo mi.” Ninu iwe kan ti Ogbeni Ghulam Ahmad Qadiani kosi Ogbeni Hakeem Noorudin, o sope” pelu ogun timole, motiri iyato. Awon arun pepepe to nse mi ti san. Eyi toleju nipe nkan omokunrin mi to manro ti mo ba sun pelu iyawo mi, oti san bayi lehin ti mo lo ogun yin. Agbara ti pada simi lara”.  

   Bakanna, ninu awon (letters) iwe ti Ogbeni Ghulam Ahmad Qadiani ko sinu iwe nla kan ti ampe ni MAKTOOBAT-E- AHMADIYYA. Vpl 5. No. 2, Ghulam Ahmad so bayi pe:  “Iranse ti wa bami nipa igbeyo mi – ni asikona ni kosi agbara fun mi lara ati ninu opolo bakanna arun itosuga, oyi kiko ati bebe lo jeki irewesi ati ibanuje bami. Leyin gbogbo arun yi, motun ni arun warapa.”

   Ninu iwe miran ti anpe ni Nuzool-e-Maseeh, Roohani Khazain vol. 18. oju ewe 587, Ogbeni Ghulam Ahmad Qadiani tun sope: Ogbeni Ghulam Ahmad Qadiani a ma fi awe die sile ninu Ramadan ti osi ma san pada lehin awe. Nitori awon arun tonse. Ojo kan, lasiko irun mogrib loja awe kan. Aile ara ma nda Ogbeni na lamu. Ninu iwe miran ti anpe ni Seerat-ul-Mahdi, apa kini oju ewe 51, eyiti Ghulam Ahmad ko so bayi pe “Hazrat Sahab ya ode. Arun kan tio jogun. Ari eri lati ara ogbeni Jamiat Baig tise batan baba re Ogbeni Jamiat pelu omo re okunrin ati omo re obinrin ti won ni arun na – won a ma se bi ode ti ori won kope. Oruko omokunrin na ni ogbeni Sher Ali ti omobinrin na nje Hurmat Bibi ti o fe Hazrat Sahab loko.

   ARUN OPOLO NINU AKOSILE OGUN AWON

   Arun ti ma mu ni da bi e eniti ori re kope je nkan ti o tipe eyi ti o tiwa litijo ti ati da aye. Eleyi ni ati deba ti omo enia ti jogun ba. Atiri ninu awon iwe atijo. Koda, ni nkan bi egberun meji si merin leyin tiawi yi ni asiripe iru arun yi a si ma dayan la’amu. Bakanna ninkan bi egberun odun ledie ni arika pe arun opolo je arun ti ma dani laamu ti kise afise. Eniti o ko akosile na ni Ogbeni Hippocrates. Bi o se se alaye ninu akosile na ni atiri ogbon ko titi do niyi.  Arun warapa, ki eyan mase radarada tabi ki eyan ma le dankanse ati bebe lo je nkan ti oti wa tipe gege bi ogbeni Hippocrates tiso ninu oro re. Os alaye pe ti obinrin ko bari orunsun, kolejeum tabi ohungbe abi ki ebibi magbeni awon nkan bayi a ma danilaamu.  Ni asiko ijoba Rome, onisegun kan tonje Galen kowe nipa arun opolo ti onsoyan dode, oni elomiran tio ni arun na, majaya, ikorira, eni to ma nbe bi ile aiye ti su, oninukunkun, okuroro. Gbogbo eleyin ni Ogbeni Galen sope latinu opolo ni o ti wa.  Ara awon to kowe ni Robert Burton ni pa arun ti o nseni di ode ni odun 1630. Ose alaye pe arun ori ati okan ni ti o mu riro ati ibanuje okan wa. Ogbeni Burton lo si ona bi a selemo eko nipa arun na. Awon nkan to nfa ni ki eyan ma kan abuku, ete, itiju, ibinu, ife ara eni tabi ki eyan padanu nkan ini.  Ojogbon kan ti a npe ni Freud ninu we tire to pe ni (Mourning and Melanch olia) ni odun 1917, o so pe awon ti won ni arun opolo yi a mafiya je arawon ati awon lya miran gege bi ki oluware male ba obinrin lo, eyi ti a mada iru eni be laamu. Iyen ni wipe ti awon ojogbon wonyi ba ni anfani lati mo ogbeni wa Mirza ni, won ba (ese alaye iru arun to nda laamu).  Gegebi ase so ni saaju pe arun to nso ni di ode tabi eniti opolo re kope tiwa ni ojo pipe eyi ti awon oni segun ati ojogbon tise alaye nipa re, ni eni, eko ti po lorisirisi pelu imo igbalode. Bakanna ni awon ojogbon so nipa nkan to ma nfa aipe opolo. Won ni akojopo omi dudu to rope mo nkan orisi risi lowa ninu ikun elomiran. Nibi ki bi ti omi dudu yi ba kojosi, oma nru soke lo sinu opolo. Eleyi lo ma mu ki gbogbo nkan rupo ki o si ma banu opoloje ki oluware ma rotutu ara re. Idamu orisi risi lomade ba. Boya awon eruku to nropo tosi njade lara Ogbeni Mirza lomu ki o ma ri orisirisi ti o fi lerope Olorun lo nba soro. Ogbeni Allama Burhanudin Nafees ninu iwe to pe ni (Guide to the Cases & Sumptons of Melancholia) rope a run opolo yi lewa lara nkan to nfun okunrin lagbara ati ba obinrin lo ti o wa ninu edo ati kun sugbon, ninu abajade eko ijinle sope inu opolo lotin wa. Awon nkan towa ninu wa le ni alebu, tio bajebe o le mu irewesi okan wa lara okunrin, iru enibe okan re konibale, yio ma damu, amarona pupo, ama so gbogbo nkan di babara, ti kosini lejehun.   Ninu Iwe Makhzan – e- Hikmat, Ogbeni Hakeem Dr. Ghulam Jeelani sope “Ikun didaru, ki ikun ma gbona, ki ebi ma fe pa ni, ati ki oluware ma gufe gbi gbona tio fe ma ko si agbari, ki inu makun ati pe ki ara ma gbona, owo ati ese tabi nigba miran ki gbogbo ara ma tutu, tabi ki oyi ma koni, ki opolo ma gbona pelu efori. Gbogbo eleyi ni apere tio ma wa fun eniti ori re fe daru.”

   Ti a ba ka gbogbo iwe ti o ti tokasi wonyi nje ale sowipe eni ti oni iru arun bayi le sope Olorun ba ohun soro tabi ki o sope Olorun ran oun nise ki agba iru eni be gbo bi? Nje se ale pe iru eni to ba te le ogbeni na ni eni ti o gba Anobi Mohameed (SW) gbo?  Anobi sope ninu ijo mi, a to bi ogbon enia tio ma pe ara re ojise Olorun . Owa ku si owo wa lati mo iru eni ti ogbeni  yi je.  Eje ki a wo nkan t awon ojobgon ati onimo ijinle so ni pa aru opolo.

   “Arun opolo yi je nkan ti o ma mu yan ma gbin erokero sokan to be to jepe were ni a ma npe  enibe. Arun yi tun le wa tie do oluware bangbona ju. Ti awon ohunje ti ko wulo ni kun ba ropo mo eruku (gas) ninu ifun, eyi ma mu ki nkan to dudu felo si opolo, eleyina ni a npe ni were to nru jade lati opolo.

   Itoju aruna: Woni oye ki eni ti o ba ni arun yi ma wase kanse ti o mu okan re re bale ti awon enia koni won lodo re, ti wonsi ma fi ife han si, ti inure ma dun ni gba kugba. O ye ki a ma fun ni oti ti a dapo mo omi, niwon ba ni a ma funmu.

 

  

   Akiyesi:- Ogbeni Mirza Ghulam Ahmed Qadirat a ma lo oti tonic pelu ogun to le fun itoju ara re.

  “Arun  opoloyi a ma yi ero dada si ikan mi ran nitori eru bi ba. Awon miran ninu alarun yi a ma lero wipe awon nkan to pamo ati nkan tio ma sele lola. To ba ya, iru eni be a ma ara re gegebi (angeli) molaika.”  Ninu iwe (Guide to the Aetiology & manifestations of disease of malauchglia by Allama Vurhnu in Nafees) Iwe na so pe ti eni to o bani arun yi ba je elesin, ama so pe ohun lese ise iyanu.

  Wonni ti a ba ti mo wipe enikan ti ni iru arun yi ri, koye ki a ma gbagbo. Nitori kosi ododokan ti a leri lodo eni be.  Eleyi wa ninu iwe Dr. Shahanawas Qudiani ninu Review of Religion, August 1926 A.D

   Ogbeni Qadani ati oti pelu Ogun oloro Awon nkan alagbara (oloro) wa ninu ogun ti Ogbeni Mirza Ghulam Ahmad Qadian ma n lo Ohun a ma so pe awon onisegun a ma fe ki a mu nkan to lagbara pelu ogun ti a ba nlo. Nitori eyi, oma nife si nkan oloro tabi ti o le la ti  mafi pelu ogun to ba nlo. Ati wipe ohun ko lodi si nkan ti o le payan bi oti. Nitoripe, kosi eniti ki lo nkan bi oti lekokam laimo at nkan oloro pelu “Ogbeni Hazrat Maseeh Mawood (Mirza Ghulam Ahamed Quadir) see ogun ti ampe ni Tiryaq-e- llahu eyi tio ni Olorun pa oun lase tio si je pe nkan oloro wa ni be. Ogun yi ni afun Hazirat Khalifat (khalifa Alakoko. Hakeem Noorudine) lati owo (Mirza Qadiani). Eleyi ni awon mejeji nlo fun bi osu  ba ki won mo le. Mi an. Ako sile ti Ogbeni mi an Mahmood Ahmad Khalifa Qadian ninu iwe Akbar Al Fazal Qadian) Vol. 17 N0 6. 19 July, 1929.

  Oti wine

   Iwo Brother mi Mohammad Hussain Sahab ki olorun ki o se alabo re. Assalam Alaikum

    Main Yah Mohammed ni a ran ni se bayi. Awon nkan ti o ma ra fun arare igo kan oti tonic  kan, ki o fi eleyisokan . Emi ni Mirza Ghulam Ahmad Qadiani. (Awon iwe Imam S.P. S) akojo iwe (collections of letters eyi ti Ogbeni Mriza Ghulam Ahmad Qadiani ko si Hakeem Mohammad Hussain Qadiani ti o ni ile Iwosan ti an pe ni Rafiq-us-seliat Lahore lati odo Dr. Aziz Ahmad Iyen  wa fesi iwe na bayi.

   Nipa ase tie ipa fun mi, mo bere lodo shop plammer, nkan to so nipe (Tonic wine) oti to le ti o ma pa yan ti owa lati U.K. Wilayat, eyi ti igo re wa ni titipa, owo re je Rs. 5 ninu iwe kan ti ampe ni Annas 8 (21.9.1933)” Sauda-e- Mirza P.39 eyi ti Hakeem Molhammad Ali ko, eniti se Oga Tibbiya College Amratsan. Eyi ri wipe, oti fojuhan pe gbogbo nkan ti mirza Ghulam Ahmad sope ohun ni Messi a ati  Mahdi ati ipe ohun ni Anobi, awon apere arun opolo ti kise ti lati odo Olorun wa. Lilo ogun lile ati oti oloro lo un je ki oro na burufun ogbeni n a. Adura mi nipe ki Olorun fun awon ara ilu Qadiani ni agboye lati tele ona toto be kojebe gbogbo omo Qadiani ti ontele Ogbeni na ni yio ni arun ti o ni.

 

Anti Ahmadiyya Movement in Islam

Dr Syed Rashid Ali

P.O. BOX : 11560

Dibba, Al-Fujairah

United Arab Emirates

E-mail : rasyed@emirates.net.ae

اضيف بواسطة :   admin       رتبته (   الادارة )
التقييم: 0 /5 ( 0 صوت )

تاريخ الاضافة: 26-11-2009

الزوار: 2614


المقالات المتشابهة
المقال السابقة
Where is the Grave of Jesus
المقالات المتشابهة
المقال التالية
False Beliefs
جديد قسم مـقـالات الموقـــع
القائمة الرئيسية
البحث
البحث في
القائمة البريدية

اشتراك

الغاء الاشتراك